Alawiiye_Iwe_Kefa_By_J__F__Odunjo-100837-380x380Alawiiye_Iwe_Kefa_By_J__F__Odunjo-100837-380x380
, ,

Alawiiye Iwe Kefa By J. F. Odunjo

Seller
5 out of 5

Ise ni ogun `se
Mura si ise ore mi
Ise ni afi ndeni giga
Bi ako ba reni fehinti
Bi ole la a ri
Bi a ko ba reni gbekele
A tera mose eni
Iya re le lowo lowo
Baba re si le leshin le kan
Bi o ba gboju le won
O te tan ni mo so fun o
Ohun ti a ko ba jiya fun
Se kii le tojo
Ohun ti a ba fara sise fun
Ni npe lowo eni
Apa lara
Igunpa ni iye kan
Bi aiye ba nfe o loni
Ti o balowo lowo
Won a ma fe o lola
Jeki o wa ni ipo atata
Aiye a ma ye o si terin-terin
Jeki o deni rago
Ko o ri bi aiye ti nyinmu si o
Eko si tun seni doga
Mura ki o ko dara-dara
Iya nbo fomo ti ko gbon
Ekun mbe fomo ti o nsa kiri
Ma fowuro sere ore mi
Mura si ise ojo nlo.

Item will be shipped in 1-2 weeks

$5.00

Based on 0 reviews

0.0 overall
0
0
0
0
0

Only logged in customers who have purchased this product may leave a review.

There are no reviews yet.

No more offers for this product!

General Inquiries

There are no inquiries yet.

You may also like…

Recently Viewed Product

  • Homia

    0 out of 5
    (0)

    Meet Homia.

    Build your Nigerian home regardless of tribe or religion and be the first to do that if you want to win. The story behind Homia is that Nigeria is a multi-cultural, multi-ethnic and multi-religious country and the player must create a family regardless of the culture or religion. It’s designed to be easy to play. You choose a family and build the family.

    Age: 5+
    No of players: 1-5
    Time (average): 20mins
    Year of Publish: 2018
    Designer: Kenechukwu Ogbuagu KC
    Publisher: NIBCARD Nig Ltd.

    SKU: n/a