Alawiiye_Iwe_Keta_By_J__F__Odunjo-100834-500x500Alawiiye_Iwe_Keta_By_J__F__Odunjo-100834-500x500
, ,

Alawiiye Iwe Keta By J. F. Odunjo

Seller
5 out of 5

Ise ni ogun `se
Mura si ise ore mi
Ise ni afi ndeni giga
Bi ako ba reni fehinti
Bi ole la a ri
Bi a ko ba reni gbekele
A tera mose eni
Iya re le lowo lowo
Baba re si le leshin le kan
Bi o ba gboju le won
O te tan ni mo so fun o
Ohun ti a ko ba jiya fun
Se kii le tojo
Ohun ti a ba fara sise fun
Ni npe lowo eni
Apa lara
Igunpa ni iye kan
Bi aiye ba nfe o loni
Ti o balowo lowo
Won a ma fe o lola
Jeki o wa ni ipo atata
Aiye a ma ye o si terin-terin
Jeki o deni rago
Ko o ri bi aiye ti nyinmu si o
Eko si tun seni doga
Mura ki o ko dara-dara
Iya nbo fomo ti ko gbon
Ekun mbe fomo ti o nsa kiri
Ma fowuro sere ore mi
Mura si ise ojo nlo.

Item will be shipped in 1-2 weeks

$5.00

Based on 0 reviews

0.0 overall
0
0
0
0
0

Only logged in customers who have purchased this product may leave a review.

There are no reviews yet.

No more offers for this product!

General Inquiries

There are no inquiries yet.

You may also like…

Recently Viewed Product

  • Irin Ajo

    0 out of 5
    (0)

    Meet Irin-Ajo.

    It means ‘Journey’ in Yoruba. The game is connecting the six geopolitical zones with their modes of transportation. Just like in the North you could use a camel to move around but in the East, there are no camels. 

    You would see the Uphill (Enugu), Riverside (to represent the southern part), the Central City (Abuja), the oceans and islands of Lagos, the Caliphate Town (Sokoto), and the Basin land. It is played using dice and token.

    Age: 6+
    No of players: 2-4
    Time (average): 20mins
    Year of Publish: 2017
    Designer: Kenechukwu Ogbuagu KC
    Publisher: NIBCARD Nig Ltd.

    SKU: n/a